1
2 Kronika 3:1
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nígbà náà, Solomoni bẹ̀rẹ̀ sí ní kọ́ ilé OLúWA ní Jerusalẹmu lórí òkè Moriah, níbi tí OLúWA ti farahan baba a rẹ̀ Dafidi. Ní orí ilẹ̀ ìpakà Arauna ará Jebusi, ibi tí Dafidi pèsè.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí 2 Kronika 3:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò