1
2 Kronika 26:5
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ó sì wá OLúWA ní ọjọ́ Sekariah, ẹni tí ó ní òye nínú ìran Ọlọ́run. Níwọ́n ọjọ́ tí ó wá ojú OLúWA, Ọlọ́run fún un ní ohun rere.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí 2 Kronika 26:5
2
2 Kronika 26:16
Ṣùgbọ́n lẹ́yìn ìgbà tí Ussiah jẹ́ alágbára tán, ìgbéraga rẹ̀ sì gbé e ṣubú. Ó sì di aláìṣòótọ́ sí OLúWA Ọlọ́run rẹ̀. Ó sì wọ ilé OLúWA láti sun tùràrí lórí pẹpẹ tùràrí.
Ṣàwárí 2 Kronika 26:16
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò