1
1 Samuẹli 12:24
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ṣùgbọ́n ẹ rí i dájú pé, ẹ bẹ̀rù OLúWA, kí ẹ sì sìn ín nínú òtítọ́ pẹ̀lú gbogbo ọkàn an yín; Ẹ kíyèsi ohun ńlá tí ó ti ṣe fún un yín.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí 1 Samuẹli 12:24
2
1 Samuẹli 12:22
Nítorí orúkọ ńlá rẹ̀ OLúWA kì yóò kọ àwọn ènìyàn rẹ̀ sílẹ̀, nítorí tí inú OLúWA dùn láti fi yín ṣe ènìyàn rẹ̀.
Ṣàwárí 1 Samuẹli 12:22
3
1 Samuẹli 12:20
Samuẹli sì dá wọn lóhùn pé, “Ẹ má bẹ̀rù, ẹ ti ṣe gbogbo búburú yìí; síbẹ̀ ẹ má ṣe yípadà kúrò lọ́dọ̀ OLúWA, ṣùgbọ́n ẹ fi gbogbo àyà yín sin OLúWA.
Ṣàwárí 1 Samuẹli 12:20
4
1 Samuẹli 12:21
Ẹ má ṣe yípadà sọ́dọ̀ àwọn òrìṣà. Wọn kò le ṣe ohun rere kan fún un yín, tàbí kí wọ́n gbà yín là, nítorí asán ni wọ́n.
Ṣàwárí 1 Samuẹli 12:21
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò