1
1 Ọba 8:56
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
“Ìbùkún ni fún OLúWA tí ó ti fi ìsinmi fún Israẹli, ènìyàn rẹ̀ bí ó ti ṣèlérí. Kò sí ọ̀rọ̀ rẹ̀ kan tí ó kùnà nínú gbogbo ìlérí rere tí ó ti ṣe láti ọwọ́ Mose ìránṣẹ́ rẹ̀ wá.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí 1 Ọba 8:56
2
1 Ọba 8:23
Ó sì wí pé: “OLúWA Ọlọ́run Israẹli, kò sí Ọlọ́run tí ó dàbí rẹ lókè ọ̀run tàbí ní ìsàlẹ̀ ilẹ̀ ìwọ tí ó pa májẹ̀mú àti àánú mọ́ pẹ̀lú àwọn ìránṣẹ́ rẹ tí ń fi gbogbo ọkàn wọn rìn níwájú rẹ.
Ṣàwárí 1 Ọba 8:23
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò