1
1 Ọba 4:29
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ọlọ́run sì fún Solomoni ní ọgbọ́n, àti òye ní ọ̀pọ̀lọpọ̀, àti ìmọ̀ gbígbòòrò òye tí a kò le è fiwé iyanrìn tí ó wà létí Òkun.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí 1 Ọba 4:29
2
1 Ọba 4:34
Àwọn ènìyàn sì ń wá láti gbogbo orílẹ̀-èdè láti gbọ́ ọgbọ́n Solomoni, láti ọ̀dọ̀ àwọn ọba ayé láti wá gbọ́ nípa ọgbọ́n rẹ̀.
Ṣàwárí 1 Ọba 4:34
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò