1
Sek 6:12
Bibeli Mimọ
Si sọ fun u pe, Bayi ni Oluwa awọn ọmọ-ogun sọ wipe, Wò ọkunrin na ti orukọ rẹ̀ njẹ ẸKA; yio si yọ ẹka lati abẹ rẹ̀ wá, yio si kọ́ tempili Oluwa
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Sek 6:12
2
Sek 6:13
On ni yio si kọ́ tempili Oluwa; on ni yio si rù ogo, yio si joko yio si jọba lori itẹ rẹ̀; on o si jẹ alufa lori itẹ̀ rẹ̀; ìmọ alafia yio si wà lãrin awọn mejeji.
Ṣàwárí Sek 6:13
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò