1
O. Daf 84:11
Bibeli Mimọ
Nitori Oluwa Ọlọrun li õrun ati asà: Oluwa yio fun ni li ore-ọfẹ ati ogo: kò si ohun rere ti yio fà sẹhin lọwọ awọn ti nrìn dede.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 84:11
2
O. Daf 84:10
Nitori pe ọjọ kan ninu agbala rẹ sanju ẹgbẹrun ọjọ lọ. Mo fẹ ki nkuku ma ṣe adena ni ile Ọlọrun mi, jù lati ma gbe agọ ìwa-buburu.
Ṣàwárí O. Daf 84:10
3
O. Daf 84:5
Ibukún ni fun enia na, ipá ẹniti o wà ninu rẹ: li ọkàn ẹniti ọ̀na rẹ wà.
Ṣàwárí O. Daf 84:5
4
O. Daf 84:2
Ọkàn mi nfà nitõtọ, o tilẹ pe ongbẹ fun agbala Oluwa: aiya mi ati ara mi nkigbe si Ọlọrun alãye.
Ṣàwárí O. Daf 84:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò