1
O. Daf 69:30
Bibeli Mimọ
Emi o fi orin yìn orukọ Ọlọrun, emi o si fi ọpẹ gbé orukọ rẹ̀ ga.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 69:30
2
O. Daf 69:13
Ṣugbọn bi o ṣe ti emi ni, iwọ li emi ngbadura mi si, Oluwa, ni igba itẹwọgba: Ọlọrun, ninu ọ̀pọlọpọ ãnu rẹ da mi lohùn, ninu otitọ igbala rẹ.
Ṣàwárí O. Daf 69:13
3
O. Daf 69:16
Oluwa, da mi lohùn; nitori ti iṣeun ifẹ rẹ dara, yipada si mi gẹgẹ bi ọ̀pọlọpọ irọnu ãnu rẹ.
Ṣàwárí O. Daf 69:16
4
O. Daf 69:33
Nitoriti Oluwa gbohùn awọn talaka, kò si fi oju pa awọn ara tubu rẹ̀ rẹ́.
Ṣàwárí O. Daf 69:33
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò