1
O. Daf 59:16
Bibeli Mimọ
Ṣugbọn emi o kọrin agbara rẹ; nitõtọ, emi o kọrin ãnu rẹ kikan li owurọ: nitori pe iwọ li o ti nṣe àbo ati ibi-asala mi li ọjọ ipọnju mi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 59:16
2
O. Daf 59:17
Iwọ, agbara mi, li emi o kọrin si: nitori Ọlọrun li àbo mi, Ọlọrun ánu mi!
Ṣàwárí O. Daf 59:17
3
O. Daf 59:9-10
Agbara rẹ̀ li emi o duro tì: nitori Ọlọrun li àbo mi. Ọlọrun ãnu mi ni yio ṣaju mi: Ọlọrun yio jẹ ki emi ri ifẹ mi lara awọn ọta mi.
Ṣàwárí O. Daf 59:9-10
4
O. Daf 59:1
ỌLỌRUN mi, gbà mi lọwọ awọn ọta mi: dãbobo mi lọwọ awọn ti o dide si mi.
Ṣàwárí O. Daf 59:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò