1
O. Daf 55:22
Bibeli Mimọ
Kó ẹrù rẹ lọ si ara Oluwa, on ni yio si mu ọ duro: on kì yio jẹ ki ẹsẹ olododo ki o yẹ̀ lai.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 55:22
2
O. Daf 55:17
Li alẹ, li owurọ, ati li ọsan, li emi o ma gbadura, ti emi o si ma kigbe kikan: on o si gbohùn mi.
Ṣàwárí O. Daf 55:17
3
O. Daf 55:23
Ṣugbọn iwọ, Ọlọrun, ni yio mu wọn sọkalẹ lọ si iho iparun: awọn enia ẹ̀jẹ ati enia ẹ̀tan kì yio pe àbọ ọjọ wọn; ṣugbọn emi o gbẹkẹle ọ.
Ṣàwárí O. Daf 55:23
4
O. Daf 55:16
Bi o ṣe ti emi ni, emi o kepè Ọlọrun; Oluwa yio si gbà mi.
Ṣàwárí O. Daf 55:16
5
O. Daf 55:18
O ti gbà ọkàn mi silẹ li alafia lọwọ ogun ti o ti dó tì mi: nitoripe pẹlu ọ̀pọlọpọ enia ni nwọn dide si mi.
Ṣàwárí O. Daf 55:18
6
O. Daf 55:1
FETI si adura mi, Ọlọrun; má si ṣe fi ara rẹ pamọ kuro ninu ẹ̀bẹ mi.
Ṣàwárí O. Daf 55:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò