1
O. Daf 5:12
Bibeli Mimọ
Nitori iwọ, Oluwa, ni yio bukún fun olododo; oju-rere ni iwọ o fi yi i ka bi asà.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 5:12
2
O. Daf 5:3
Ohùn mi ni iwọ o gbọ́ li owurọ, Oluwa, li owurọ li emi o gbà adura mi si ọ, emi o si ma wòke.
Ṣàwárí O. Daf 5:3
3
O. Daf 5:11
Nigbana ni gbogbo awọn ti ngbẹkẹle ọ yio yọ̀; lai nwọn o ma ho fun ayọ̀, nitoriti iwọ dabobo wọn: ati awọn ti o fẹ orukọ rẹ pẹlu yio ma yọ̀ ninu rẹ.
Ṣàwárí O. Daf 5:11
4
O. Daf 5:8
Tọ́ mi, Oluwa, ninu ododo rẹ, nitori awọn ọta mi: mu ọ̀na rẹ tọ́ tàra niwaju mi.
Ṣàwárí O. Daf 5:8
5
O. Daf 5:2
Fi eti si ohùn ẹkún mi, Ọba mi, ati Ọlọrun mi: nitoripe ọdọ rẹ li emi o ma gbadura si.
Ṣàwárí O. Daf 5:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò