1
O. Daf 47:1
Bibeli Mimọ
ẸNYIN enia, gbogbo ẹ ṣapẹ; ẹ fi ohùn ayọ̀ hó ihó iṣẹgun si Ọlọrun.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 47:1
2
O. Daf 47:2
Nitori Oluwa Ọga-ogo li ẹ̀ru; on li ọba nla lori ilẹ-aiye gbogbo.
Ṣàwárí O. Daf 47:2
3
O. Daf 47:7
Nitori Ọlọrun li Ọba gbogbo aiye: ẹ fi oye kọrin iyìn.
Ṣàwárí O. Daf 47:7
YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò