1
O. Daf 150:6
Bibeli Mimọ
Jẹ ki ohun gbogbo ti o li ẹmi ki o yìn Oluwa. Ẹ fi iyìn fun Oluwa.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 150:6
2
O. Daf 150:1
Ẹ fi iyìn fun Oluwa. Ẹ fi iyìn fun Ọlọrun ninu ibi mimọ́ rẹ̀; yìn i ninu ofurufu oju-ọrun agbara rẹ̀.
Ṣàwárí O. Daf 150:1
3
O. Daf 150:2
Yìn i nitori iṣẹ agbara rẹ̀: yìn i gẹgẹ bi titobi nla rẹ̀.
Ṣàwárí O. Daf 150:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò