1
O. Daf 148:13
Bibeli Mimọ
Ki nwọn ki o ma yìn orukọ Oluwa; nitori orukọ rẹ̀ nikan li o li ọlá; ogo rẹ̀ bori aiye on ọrun.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 148:13
2
O. Daf 148:5
Jẹ ki nwọn ki o ma yìn orukọ Oluwa; nitori ti on paṣẹ, a si da wọn.
Ṣàwárí O. Daf 148:5
3
O. Daf 148:1
Ẹ fi iyìn fun Oluwa, Ẹ fi iyìn fun Oluwa lati ọrun wá; ẹ fi iyìn fun u ni ibi giga.
Ṣàwárí O. Daf 148:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò