1
O. Daf 141:3
Bibeli Mimọ
Oluwa, fi ẹṣọ́ siwaju ẹnu mi; pa ilẹkun ète mi mọ́.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 141:3
2
O. Daf 141:4
Máṣe fà aiya mi si ohun ibi kan, lati ma ba awọn ti nṣiṣẹ ẹ̀ṣẹ ṣiṣẹ buburu; má si jẹ ki emi ki o jẹ ninu ohun didùn wọn.
Ṣàwárí O. Daf 141:4
3
O. Daf 141:1-2
OLUWA, emi kigbe pè ọ: yara si ọdọ mi; fi eti si ohùn mi, nigbati mo ba nkepè ọ. Jẹ ki adura mi ki o wá si iwaju rẹ bi ẹbọ turari; ati igbé ọwọ mi soke bi ẹbọ aṣãlẹ.
Ṣàwárí O. Daf 141:1-2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò