1
O. Daf 130:5
Bibeli Mimọ
Emi duro dè Oluwa, ọkàn mi duro, ati ninu ọ̀rọ rẹ̀ li emi nṣe ireti.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 130:5
2
O. Daf 130:4
Nitori idariji wà lọdọ rẹ, ki a le ma bẹ̀ru rẹ.
Ṣàwárí O. Daf 130:4
3
O. Daf 130:6
Ọkàn mi duro dè Oluwa, jù awọn ti nṣọ́na owurọ lọ, ani jù awọn ti nṣọ́na owurọ lọ.
Ṣàwárí O. Daf 130:6
4
O. Daf 130:2
Oluwa, gbohùn mi, jẹ ki eti rẹ ki o tẹ́ silẹ si ohùn ẹ̀bẹ mi.
Ṣàwárí O. Daf 130:2
5
O. Daf 130:1
LATI inu ibu wá li emi kepe ọ, Oluwa.
Ṣàwárí O. Daf 130:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò