1
Num 12:8
Bibeli Mimọ
On li emi mbá sọ̀rọ li ẹnu ko ẹnu, ati ni gbangba, ki si iṣe li ọ̀rọ ti o ṣe òkunkun; apẹrẹ OLUWA li on o si ri: njẹ nitori kili ẹnyin kò ṣe bẹ̀ru lati sọ̀rọ òdi si Mose iranṣẹ mi?
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Num 12:8
2
Num 12:3
Ṣugbọn ọkunrin na Mose, o ṣe ọlọkàn tutù jù gbogbo enia lọ ti mbẹ lori ilẹ.
Ṣàwárí Num 12:3
3
Num 12:6
O si wipe, Ẹ gbọ́ ọ̀rọ mi nisisiyi: bi wolĩ OLUWA ba mbẹ ninu nyin, emi OLUWA yio farahàn fun u li ojuran, emi o si bá a sọ̀rọ li oju-alá.
Ṣàwárí Num 12:6
4
Num 12:7
Mose iranṣẹ mi kò ri bẹ̃, olõtọ ni ninu gbogbo ile mi.
Ṣàwárí Num 12:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò