1
Mak 3:35
Bibeli Mimọ
Nitori ẹnikẹni ti o ba ṣe ifẹ Ọlọrun, on na li arakunrin mi, ati arabinrin mi, ati iya mi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Mak 3:35
2
Mak 3:28-29
Lõtọ ni mo wi fun nyin, Gbogbo ẹ̀ṣẹ li a o dari wọn jì awọn ọmọ enia, ati gbogbo ọrọ-odi nipa eyiti nwọn o ma fi sọrọ-odi: Ṣugbọn ẹniti o ba sọrọ-odi si Ẹmi Mimọ́ kì yio ni idariji titi lai, ṣugbọn o wà ninu ewu ẹbi ainipẹkun
Ṣàwárí Mak 3:28-29
3
Mak 3:24-25
Bi ijọba kan ba si yàpa si ara rẹ̀, ijọba na kì yio le duro. Bi ile kan ba si yàpa si ara rẹ̀, ile na kì yio le duro.
Ṣàwárí Mak 3:24-25
4
Mak 3:11
Ati awọn ẹmi aimọ́, nigbàkugba ti nwọn ba ri i, nwọn a wolẹ niwaju rẹ̀, nwọn a kigbe soke, wipe, Iwọ li Ọmọ Ọlọrun.
Ṣàwárí Mak 3:11
YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò