1
Mik 7:18
Bibeli Mimọ
Tani Ọlọrun bi iwọ, ti o ndari aiṣedede jì, ti o nre iyokù ini rẹ̀ kọja? kò dá ibinu rẹ̀ duro titi lai, nitori on ni inudidun si ãnu.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Mik 7:18
2
Mik 7:7
Nitorina emi o ni ireti si Oluwa: emi o duro de Ọlọrun igbala mi: Ọlọrun mi yio gbọ́ temi.
Ṣàwárí Mik 7:7
3
Mik 7:19
Yio yipadà, yio ni iyọnú si wa; yio si tẹ̀ aiṣedede wa ba; iwọ o si sọ gbogbo ẹ̀ṣẹ wọn sinu ọgbun okun.
Ṣàwárí Mik 7:19
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò