1
Lef 20:13
Bibeli Mimọ
Ati ọkunrin ti o ba bá ọkunrin dàpọ, bi ẹni ba obinrin dàpọ, awọn mejeji li o ṣe ohun irira: pipa li a o pa wọn; ẹ̀jẹ wọn yio wà lori wọn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Lef 20:13
2
Lef 20:7
Nitorina ẹnyin yà ara nyin simimọ́, ki ẹnyin ki o si jẹ́ mimọ́: nitoripe Emi li OLUWA Ọlọrun nyin.
Ṣàwárí Lef 20:7
3
Lef 20:26
Ki ẹnyin ki o si jẹ́ mimọ́ fun mi: nitoripe mimọ́ li Emi OLUWA, mo si ti yà nyin sọ̀tọ kuro ninu awọn orilẹ-ède, ki ẹnyin ki o le jẹ́ ti emi.
Ṣàwárí Lef 20:26
4
Lef 20:8
Ki ẹnyin ki o si ma pa ìlana mi mọ́, ki ẹnyin si ma ṣe wọn: Emi li OLUWA ti nyà nyin simimọ́.
Ṣàwárí Lef 20:8
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò