1
Lef 18:22
Bibeli Mimọ
Iwọ kò gbọdọ bá ọkunrin dápọ bi obinrin: irira ni.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Lef 18:22
2
Lef 18:23
Bẹ̃ni iwọ kò gbọdọ bá ẹranko kan dàpọ, lati fi i bà ara rẹ jẹ́: bẹ̃ni obinrin kan kò gbọdọ duro niwaju ẹranko kan lati dubulẹ tì i: idaru-dàpọ ni.
Ṣàwárí Lef 18:23
3
Lef 18:21
Iwọ kò si gbọdọ fi irú-ọmọ rẹ kan fun Moleki, bẹ̃ni iwọ kò gbọdọ bà orukọ Ọlọrun rẹ jẹ́: Emi li OLUWA.
Ṣàwárí Lef 18:21
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò