1
Ẹk. Jer 1:1
Bibeli Mimọ
BAWO ni ilu ṣe joko nikan, eyi ti o ti kún fun enia! o wà bi opó! on ti iṣe ẹni-nla lãrin awọn orilẹ-ède! ọmọ-alade obinrin lãrin igberiko, on di ẹrú!
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Ẹk. Jer 1:1
2
Ẹk. Jer 1:2
On sọkun gidigidi li oru, omije rẹ̀ si wà ni ẹ̀rẹkẹ rẹ̀: lãrin gbogbo awọn olufẹ rẹ̀, kò ni ẹnikẹni lati tù u ninu: gbogbo awọn ọrẹ rẹ̀ ti ba a lo ẹ̀tan, nwọn di ọta rẹ̀.
Ṣàwárí Ẹk. Jer 1:2
3
Ẹk. Jer 1:20
Wò o, Oluwa: nitoriti emi wà ninu ipọnju: inu mi nhó; ọkàn mi yipada ninu mi; nitoriti emi ti ṣọ̀tẹ gidigidi: lode, idà sọni di alailọmọ, ni ile, o dabi ikú!
Ṣàwárí Ẹk. Jer 1:20
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò