1
Job 36:11
Bibeli Mimọ
Bi nwọn ba gbagbọ, ti nwọn si sin i, nwọn o lò ọjọ wọn ninu ìrọra, ati ọdun wọn ninu afẹ́.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Job 36:11
2
Job 36:5
Kiyesi i, Ọlọrun li agbara, kò si gàn ẹnikẹni, o li agbara ni ipá ati oye.
Ṣàwárí Job 36:5
3
Job 36:15
On gba otoṣi ninu ipọnju rẹ̀, a si ṣi wọn li eti ninu inilara.
Ṣàwárí Job 36:15
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò