1
Job 23:10
Bibeli Mimọ
Ṣugbọn on mọ̀ ọ̀na ti emi ntọ̀, nigbati o ba dan mi wò, emi o jade bi wura.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Job 23:10
2
Job 23:12
Bẹ̃ni emi kò pada sẹhin kuro ninu ofin ẹnu rẹ̀, emi si pa ọ̀rọ ẹnu rẹ̀ mọ́ jù ofin inu mi lọ.
Ṣàwárí Job 23:12
3
Job 23:11
Ẹsẹ mi ti tẹle ipasẹ irin rẹ, ọ̀na rẹ̀ ni mo ti kiyesi, ti nkò si yà kuro.
Ṣàwárí Job 23:11
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò