1
Isa 44:3
Bibeli Mimọ
Nitori emi o dà omi lu ẹniti ongbẹ ngbẹ, ati iṣàn-omi si ilẹ gbigbẹ: emi o dà ẹmi mi si iru rẹ, ati ibukun mi si iru-ọmọ rẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Isa 44:3
2
Isa 44:6
Bayi ni Oluwa wi, Ọba Israeli, ati Olurapada rẹ, Oluwa awọn ọmọ-ogun; Emi ni ẹni-ikini, ati ẹni-ikẹhin; ati lẹhin mi ko si Ọlọrun kan.
Ṣàwárí Isa 44:6
3
Isa 44:22
Mo ti pa irekọja rẹ rẹ́, bi awọsanma ṣiṣú dùdu, ati ẹ̀ṣẹ rẹ, bi kũku: yipada sọdọ mi; nitori mo ti rà ọ pada.
Ṣàwárí Isa 44:22
4
Isa 44:8
Ẹ má bẹ̀ru, ẹ má si foyà; emi ko ha ti mu nyin gbọ́ lati igba na wá, nkò ha si ti sọ ọ? ẹnyin na ni ẹlẹri mi. Ọlọrun kan mbẹ lẹhin mi bi? kò si Apata kan, emi ko mọ̀ ọkan.
Ṣàwárí Isa 44:8
5
Isa 44:2
Bayi ni Oluwa wi, ẹniti o dá ọ, ti o mọ ọ lati inu wá, ti yio si ràn ọ lọwọ; Má bẹ̀ru, iwọ Jakobu, iranṣẹ mi; ati iwọ Jeṣuruni ti mo ti yàn.
Ṣàwárí Isa 44:2
YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò