1
Esek 8:3
Bibeli Mimọ
O si nà àworan ọwọ́ jade, o si mu mi ni ìdi-irun ori mi; ẹmi si gbe mi soke lagbedemeji aiye on ọrun, o si mu mi wá ni iran Ọlọrun si Jerusalemu, si ilẹkun ẹnu-ọ̀na ti inu to kọju si ariwa; nibiti ijoko ere owu wà ti nmu ni jowu.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Esek 8:3
2
Esek 8:12
Nigbana li o si wi fun mi pe, Ọmọ enia iwọ ri ohun ti awọn agbà ile Israeli nṣe li okunkùn, olukuluku ninu iyará oriṣa tirẹ̀? nitori nwọn wipe, Oluwa kò ri wa; Oluwa ti kọ̀ aiye silẹ.
Ṣàwárí Esek 8:12
3
Esek 8:18
Emi pẹlu yio si fi irúnu ba wọn lò: oju mi kì yio dasi, bẹ̃li emi kì yio ṣãnu: ati bi o tilẹ ṣepe nwọn fi ohùn rara kigbe li eti mi, sibẹ emi kì yio gbọ́ ti wọn.
Ṣàwárí Esek 8:18
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò