1
Esek 15:8
Bibeli Mimọ
Emi o si sọ ilẹ na di ahoro, nitori ti nwọn ti dẹṣẹ, ni Oluwa Ọlọrun wi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Esek 15:8
2
Esek 15:7
Emi o si doju mi kọ wọn, nwọn o jade kuro ninu iná kan, iná miran yio si jo wọn, ẹnyin o si mọ̀ pe emi li Oluwa, nigbati mo ba dojukọ wọn.
Ṣàwárí Esek 15:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò