1
Esek 11:19
Bibeli Mimọ
Emi o si fun wọn li ọkàn kan, emi o si fi ẹmi titun sinu nyin; emi o si mu ọkàn okuta kuro lara wọn, emi o si fun wọn li ọkàn ẹran
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Esek 11:19
2
Esek 11:20
Ki wọn le rìn ninu aṣẹ mi, ki wọn si le pa ilana mi mọ, ki nwọn si ṣe wọn: nwọn o si jẹ enia mi, emi o si jẹ Ọlọrun wọn.
Ṣàwárí Esek 11:20
3
Esek 11:17
Nitorina wipe, Bayi li Oluwa Ọlọrun wi, pe, Emi tilẹ kó nyin kuro lọdọ awọn orilẹ-ède; emi o si kó nyin jọ lati ilẹ ti a ti tú nyin ká si, emi o si fun nyin ni ilẹ Israeli.
Ṣàwárí Esek 11:17
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò