1
Deu 26:19
Bibeli Mimọ
On o si mu ọ ga jù orilẹ-ède gbogbo lọ ti o dá, ni ìyin, li orukọ, ati ọlá; ki iwọ ki o le ma jẹ́ enia mimọ́ fun OLUWA Ọlọrun rẹ, bi o ti sọ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Deu 26:19
2
Deu 26:18
OLUWA si jẹwọ rẹ li oni pe iwọ o ma jẹ́ enia ọ̀tọ fun ara rẹ̀, bi on ti ṣe ileri fun ọ, ati pe iwọ o ma pa gbogbo aṣẹ rẹ̀ mọ́
Ṣàwárí Deu 26:18
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò