1
Amo 5:24
Bibeli Mimọ
Ṣugbọn jẹ ki idajọ ki o ṣàn silẹ bi omi, ati ododo bi iṣàn omi nla.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Amo 5:24
2
Amo 5:14
Ẹ ma wá ire, kì isi iṣe ibi, ki ẹ ba le yè; bẹ̃ni Oluwa, Ọlọrun awọn ọmọ-ogun, yio si pẹlu nyin, bi ẹnyin ti wi.
Ṣàwárí Amo 5:14
3
Amo 5:15
Ẹ korira ibi, ẹ si fẹ́ ire, ki ẹ si fi idajọ gunlẹ ni bodè; boya Oluwa Ọlọrun awọn ọmọ-ogun yio ṣe ojurere si iyokù Josefu.
Ṣàwárí Amo 5:15
4
Amo 5:4
Nitori bayi li Oluwa wi fun ile Israeli, ẹ wá mi, ẹnyin o si yè
Ṣàwárí Amo 5:4
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò