1
Iṣe Apo 4:12
Bibeli Mimọ
Kò si si igbala lọdọ ẹlomiran: nitori kò si orukọ miran labẹ ọrun ti a fifunni ninu enia, nipa eyiti a le fi gbà wa là.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Iṣe Apo 4:12
2
Iṣe Apo 4:31
Nigbati nwọn gbadura tan, ibi ti nwọn gbé pejọ si mi titi; gbogbo wọn si kún fun Ẹmí Mimọ́, nwọn si nfi igboiya sọ ọ̀rọ Ọlọrun.
Ṣàwárí Iṣe Apo 4:31
3
Iṣe Apo 4:29
Njẹ nisisiyi, Oluwa, kiyesi ikilọ wọn: ki o si fifun awọn ọmọ-ọdọ rẹ lati mã fi igboiya gbogbo sọ ọ̀rọ rẹ.
Ṣàwárí Iṣe Apo 4:29
4
Iṣe Apo 4:11
Eyi li okuta ti a ti ọwọ́ ẹnyin ọmọle kọ̀ silẹ, ti o si di pàtaki igun ile.
Ṣàwárí Iṣe Apo 4:11
5
Iṣe Apo 4:13
Nigbati nwọn si kiyesi igboiya Peteru on Johanu, ti nwọn si mọ̀ pe, alaikẹkọ ati òpe enia ni nwọn, ẹnu yà wọn; nwọn si woye wọn pe, nwọn a ti ma ba Jesu gbé.
Ṣàwárí Iṣe Apo 4:13
6
Iṣe Apo 4:32
Ijọ awọn ti o gbagbọ́ si wà li ọkàn kan ati inu kan: kò si si ẹnikan ti o pè ohun kan ninu ohun ini rẹ̀ ni ti ara rẹ̀: ṣugbọn gbogbo nwọn ni gbogbo nkan ṣọkan.
Ṣàwárí Iṣe Apo 4:32
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò