1
Iṣe Apo 24:16
Bibeli Mimọ
Ninu eyi li emi si nṣe idaraya, lati ni ẹri-ọkàn ti kò li ẹ̀ṣẹ sipa ti Ọlọrun, ati si enia nigbagbogbo.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Iṣe Apo 24:16
2
Iṣe Apo 24:25
Bi o si ti nsọ asọye nipa ti ododo ati airekọja ati idajọ ti mbọ̀, ẹ̀ru ba Feliksi, o dahùn wipe, Mã lọ nisisiyi na; nigbati mo ba si ni akokò ti o wọ̀, emi o ranṣẹ pè ọ.
Ṣàwárí Iṣe Apo 24:25
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò