1
Iṣe Apo 18:10
Bibeli Mimọ
Nitoriti emi wà pẹlu rẹ, kò si si ẹniti yio dide si ọ lati pa ọ lara: nitori mo li enia pupọ ni ilu yi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Iṣe Apo 18:10
2
Iṣe Apo 18:9
Oluwa si sọ fun Paulu li oru li ojuran pe, Má bẹ̀ru, sá mã sọ, má si ṣe pa ẹnu rẹ mọ́
Ṣàwárí Iṣe Apo 18:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò