1
II. A. Ọba 18:5
Bibeli Mimọ
O gbẹkẹle Oluwa Ọlọrun Israeli; ati lẹhin rẹ̀ kò si ẹniti o dabi rẹ̀ ninu gbogbo awọn ọba Juda, bẹ̃ni ṣãju rẹ̀ kò si ẹnikan.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí II. A. Ọba 18:5
2
II. A. Ọba 18:6
Nitoriti o faramọ Oluwa, kò si lọ kuro lẹhin rẹ̀, ṣugbọn o pa ofin rẹ̀ wọnni mọ, ti Oluwa ti pa li aṣẹ fun Mose.
Ṣàwárí II. A. Ọba 18:6
3
II. A. Ọba 18:7
Oluwa si wà pẹlu rẹ̀; o si ṣe rere nibikibi ti o ba jade lọ: o si ṣọ̀tẹ si ọba Assiria, kò si sìn i mọ.
Ṣàwárí II. A. Ọba 18:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò