1
I. A. Ọba 8:56
Bibeli Mimọ
Ibukún ni fun Oluwa ti o ti fi isimi fun Israeli enia rẹ̀, gẹgẹ bi gbogbo eyiti o ti ṣe ileri: kò kù ọ̀rọ kan ninu gbogbo ileri rere rẹ̀ ti o ti ṣe lati ọwọ Mose, iranṣẹ rẹ̀ wá.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí I. A. Ọba 8:56
2
I. A. Ọba 8:23
O si wipe, Oluwa Ọlọrun Israeli, kò si Ọlọrun ti o dabi rẹ loke ọrun, tabi ni isalẹ ilẹ, ti ipa majẹmu ati ãnu mọ pẹlu awọn iranṣẹ rẹ ti nfi gbogbo ọkàn wọn rin niwaju rẹ
Ṣàwárí I. A. Ọba 8:23
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò