1
ORIN SOLOMONI 1:2
Yoruba Bible
Wá fi ẹnu kò mí lẹ́nu, nítorí ìfẹ́ rẹ dára ju ọtí waini lọ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN SOLOMONI 1:2
2
ORIN SOLOMONI 1:4
Fà mí mọ́ra, jẹ́ kí á ṣe kíá, ọba ti mú mi wọ yàrá rẹ̀. Inú wa yóo máa dùn, a óo sì máa yọ̀ nítorí rẹ a óo gbé ìfẹ́ rẹ ga ju ọtí waini lọ; abájọ tí gbogbo àwọn obinrin ṣe fẹ́ràn rẹ!
Ṣàwárí ORIN SOLOMONI 1:4
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò