1
ORIN DAFIDI 57:1
Yoruba Bible
Ṣàánú mi, Ọlọrun, ṣàánú mi, nítorí ìwọ ni ààbò mi; abẹ́ òjìji apá rẹ ni n óo fi ṣe ààbò mi, títí gbogbo àjálù wọnyi yóo fi kọjá.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 57:1
2
ORIN DAFIDI 57:10
Nítorí pé ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ tóbi, ó ga ju ọ̀run lọ, òtítọ́ rẹ sì kan ojú ọ̀run.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 57:10
3
ORIN DAFIDI 57:2
Mo ké pe Ọlọrun Ọ̀gá Ògo, Ọlọrun tí ó mú èrò rẹ̀ ṣẹ fún mi.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 57:2
4
ORIN DAFIDI 57:11
Gbé ara rẹ ga, Ọlọrun, gbé ara rẹ ga ju ọ̀run lọ, kí ògo rẹ sì tàn ká gbogbo ayé.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 57:11
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò