1
ORIN DAFIDI 44:8
Yoruba Bible
Ìwọ Ọlọrun ni a fi ń yangàn nígbà gbogbo; a óo sì máa fi ọpẹ́ fún orúkọ rẹ títí lae.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 44:8
2
ORIN DAFIDI 44:6-7
Nítorí pé kì í ṣe ọrun mi ni mo gbẹ́kẹ̀lé; idà mi kò sì le gbà mí. Ṣugbọn ìwọ ni o gbà wá lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wa, o sì dójú ti àwọn tí ó kórìíra wa.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 44:6-7
3
ORIN DAFIDI 44:26
Gbéra nílẹ̀, kí o ràn wá lọ́wọ́! Gbà wá sílẹ̀ nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 44:26
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò