1
ORIN DAFIDI 35:1
Yoruba Bible
OLUWA, gbógun ti àwọn tí ń gbógun tì mí; gbé ìjà ko àwọn tí ń bá mi jà!
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 35:1
2
ORIN DAFIDI 35:27
Kí àwọn tí ń wá ìdáláre mi máa hó ìhó ayọ̀, kí inú wọn sì máa dùn, kí wọ́n máa wí títí ayé pé, “OLUWA tóbi, inú rẹ̀ dùn sí alaafia àwọn iranṣẹ rẹ̀.”
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 35:27
3
ORIN DAFIDI 35:28
Nígbà náà ni n óo máa sọ̀rọ̀ òdodo rẹ, n óo sì máa yìn ọ́ tọ̀sán-tòru.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 35:28
4
ORIN DAFIDI 35:10
N óo fi gbogbo ara wí pé, “OLUWA, ta ni ó dàbí rẹ? Ìwọ ni ò ń gba aláìlágbára lọ́wọ́ ẹni tí ó lágbára tí o sì ń gba aláìlágbára ati aláìní lọ́wọ́ ẹni tí ó fẹ́ fi wọ́n ṣe ìjẹ.”
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 35:10
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò