1
ORIN DAFIDI 130:5
Yoruba Bible
Mo gbẹ́kẹ̀lé OLUWA, àní, mo gbé ọkàn mi lé e, mo sì ní ìrètí ninu ọ̀rọ̀ rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 130:5
2
ORIN DAFIDI 130:4
Ṣugbọn ní ìkáwọ́ rẹ ni ìdáríjì wà, kí á lè máa bẹ̀rù rẹ.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 130:4
3
ORIN DAFIDI 130:6
Mò ń retí rẹ, OLUWA, ju bí àwọn aṣọ́de ti máa ń retí kí ilẹ̀ mọ́ lọ, àní, ju bí àwọn aṣọ́de, ti máa ń retí pé kí ilẹ̀ mọ́.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 130:6
4
ORIN DAFIDI 130:2
OLUWA, gbóhùn mi, dẹtí sí ohùn ẹ̀bẹ̀ mi.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 130:2
5
ORIN DAFIDI 130:1
Ninu ìṣòro ńlá ni mò ń ké pè ọ́, OLUWA!
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 130:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò