1
ORIN DAFIDI 120:1
Yoruba Bible
OLUWA ni mo ké pè, nígbà tí mo wà ninu ìpọ́njú, ó sì dá mi lóhùn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 120:1
2
ORIN DAFIDI 120:2
OLUWA, gbà mí lọ́wọ́ àwọn èké, ati lọ́wọ́ àwọn ẹlẹ́tàn.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 120:2
YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò