1
ORIN DAFIDI 109:30
Yoruba Bible
N óo máa fi ẹnu mi yin OLUWA gidigidi, àní, n óo máa yìn ín ní àwùjọ ọ̀pọ̀ eniyan.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 109:30
2
ORIN DAFIDI 109:26
Ràn mí lọ́wọ́, OLUWA, Ọlọrun mi, gbà mí, nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 109:26
3
ORIN DAFIDI 109:31
Nítorí pé ó dúró ti aláìní láti gbà á lọ́wọ́ àwọn tí ó dájọ́ ikú fún un.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 109:31
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò