1
ORIN DAFIDI 104:34
Yoruba Bible
Kí àṣàrò ọkàn mi kí ó dùn mọ́ ọn ninu nítorí mo láyọ̀ ninu OLUWA.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 104:34
2
ORIN DAFIDI 104:33
N óo kọrin ìyìn sí OLUWA níwọ̀n ìgbà tí mo bá wà láàyè. N óo máa kọrin ìyìn sí Ọlọrun mi, níwọ̀n ìgbà tí ẹ̀mí mi bá ń bẹ.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 104:33
3
ORIN DAFIDI 104:1
Yin OLUWA, ìwọ ọkàn mi, OLUWA, Ọlọrun mi, ó tóbi pupọ, ọlá ati iyì ni ó wọ̀ bí ẹ̀wù.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 104:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò