1
ÌWÉ ÒWE 28:13
Yoruba Bible
Ẹni tí ó bo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ mọ́lẹ̀ kò ní ṣe rere, ṣugbọn ẹni tí ó jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, tí ó sì kọ̀ ọ́ sílẹ̀, yóo rí àánú gbà.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 28:13
2
ÌWÉ ÒWE 28:26
Òmùgọ̀ ni ẹni tí ó gbẹ́kẹ̀lé ara rẹ̀, ẹni tí ń fi ọgbọ́n rìn yóo là.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 28:26
3
ÌWÉ ÒWE 28:1
Àwọn eniyan burúkú a máa sá, nígbà tí ẹnikẹ́ni kò lé wọn, ṣugbọn olódodo a máa láyà bíi kinniun.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 28:1
4
ÌWÉ ÒWE 28:14
Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí ó ń bẹ̀rù OLUWA nígbà gbogbo, ṣugbọn ẹni tí ó sé ọkàn rẹ̀ le yóo bọ́ sinu ìyọnu.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 28:14
5
ÌWÉ ÒWE 28:27
Ẹni tí ó ta talaka lọ́rẹ kò ní ṣe aláìní, ṣugbọn ẹni tí ó fojú pamọ́ fún wọn, yóo gba ègún.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 28:27
6
ÌWÉ ÒWE 28:23
Ẹni tí ó bá eniyan wí, yóo rí ojurere níkẹyìn, ju ẹni tí ń pọ́n eniyan lọ.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 28:23
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò