1
ÌWÉ ÒWE 24:3
Yoruba Bible
Ọgbọ́n ni a fi ń kọ́lé, òye ni a fi ń fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 24:3
2
ÌWÉ ÒWE 24:17
Má yọ̀ nígbà tí ọ̀tá rẹ bá ṣubú, má sì jẹ́ kí inú rẹ dùn bí ó bá kọsẹ̀
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 24:17
3
ÌWÉ ÒWE 24:33-34
Oorun díẹ̀, òògbé díẹ̀, ìkáwọ́ gbera díẹ̀ láti sinmi, bẹ́ẹ̀ ni òṣì yóo ṣe dé bá ọ bíi kí olè yọ sí eniyan, àìní yóo sì wọlé tọ̀ ọ́ bí ẹni tí ó di ihamọra ogun.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 24:33-34
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò