1
LEFITIKU 11:45
Yoruba Bible
Nítorí èmi ni OLUWA tí ó ko yín jáde láti ilẹ̀ Ijipti wá, láti jẹ́ Ọlọrun yín; nítorí náà, ẹ níláti jẹ́ mímọ́, nítorí pé, mímọ́ ni èmi Ọlọrun.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí LEFITIKU 11:45
2
LEFITIKU 11:44
Nítorí pé, èmi ni OLUWA Ọlọrun yín, ẹ ya ara yín sí mímọ́, kí ẹ sì jẹ́ mímọ́, nítorí mímọ́ ni èmi Ọlọrun. Ẹ kò gbọdọ̀ fi ohunkohun tí ń fi àyà fà lórí ilẹ̀ sọ ara yín di aláìmọ́.
Ṣàwárí LEFITIKU 11:44
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò