1
JONA 2:2
Yoruba Bible
ó ní, “Ninu ìpọ́njú mi, mo ké pe OLUWA, ó sì dá mi lóhùn, mo ké pè é láti inú isà òkú, ó sì gbóhùn mi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí JONA 2:2
2
JONA 2:7
Nígbà tí ẹ̀mí mi ń bọ́ lọ, mo gbadura sí ìwọ OLUWA, o sì gbọ́ adura mi ninu tẹmpili mímọ́ rẹ.
Ṣàwárí JONA 2:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò