1
JEREMAYA 12:1
Yoruba Bible
Olódodo ni ọ́, OLUWA, nígbà tí mo bá ń fẹjọ́ sùn ọ́; sibẹ n óo ro ẹjọ́ mi níwájú rẹ. Kí ló dé tí nǹkan ń dára fún àwọn eniyan burúkú?
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí JEREMAYA 12:1
2
JEREMAYA 12:2
O gbìn wọ́n, wọ́n ta gbòǹgbò; wọ́n dàgbà, wọ́n so èso; orúkọ rẹ kò jìnnà sẹ́nu wọn, ṣugbọn ọkàn wọn jìnnà sí ọ.
Ṣàwárí JEREMAYA 12:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò