1
ÀWỌN ADÁJỌ́ 21:25
Yoruba Bible
Kò sí ọba ní ilẹ̀ Israẹli ní gbogbo àkókò náà, olukuluku bá bẹ̀rẹ̀ sí ṣe bí ó ti tọ́ ní ojú ara rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÀWỌN ADÁJỌ́ 21:25
2
ÀWỌN ADÁJỌ́ 21:1
Àwọn ọmọ Israẹli ti búra nígbà tí wọ́n wà ní Misipa pé, “Ẹnikẹ́ni ninu wa kò ní fi ọmọ rẹ̀ fún ará Bẹnjamini.”
Ṣàwárí ÀWỌN ADÁJỌ́ 21:1
YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò