1
JẸNẸSISI 38:10
Yoruba Bible
Ohun tí Onani ń ṣe yìí kò dùn mọ́ Ọlọrun ninu, Ọlọrun bá pa òun náà.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí JẸNẸSISI 38:10
2
JẸNẸSISI 38:9
Ṣugbọn Onani mọ̀ pé ọmọ tí opó náà bá bí kò ní jẹ́ ti òun, nítorí náà, nígbàkúùgbà tí ó bá ń bá opó yìí lòpọ̀, yóo sì da nǹkan ọkunrin rẹ̀ sílẹ̀, kí ó má baà bí ọmọ tí yóo rọ́pò arakunrin rẹ̀.
Ṣàwárí JẸNẸSISI 38:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò